Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 15:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Akisa dá baba rẹ̀ lóhùn pé, “Fún mi ní ẹ̀bùn, níwọ̀n ìgbà tí o ti fún mi ní ilẹ̀ Nẹgẹbu, fún mi ní àwọn orísun omi pẹlu.” Kalebu bá fún un ní àwọn orísun omi tí wọ́n wà lókè ati àwọn tí wọ́n wà ní ìsàlẹ̀.

Ka pipe ipin Joṣua 15

Wo Joṣua 15:19 ni o tọ