Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 15:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Akisa dé ọ̀dọ̀ ọkọ rẹ̀, ó rọ ọkọ rẹ̀ pé kí ó tọrọ ilẹ̀ kan lọ́wọ́ baba òun. Ní ọjọ́ kan, bí Akisa ti sọ̀kalẹ̀ ní orí kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ rẹ̀, baba rẹ̀ bi í pé, “Kí ni ò ń fẹ́?”

Ka pipe ipin Joṣua 15

Wo Joṣua 15:18 ni o tọ