Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 15:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ààlà náà tún yípo lọ sí ìwọ̀ oòrùn Baala, sí apá òkè Seiri, lọ sí apá ìhà àríwá òkè Jearimu (tí a tún ń pè ní Kesaloni), ó bá tún dà gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́ lọ sí Beti Ṣemeṣi títí dé ìkọjá Timna.

Ka pipe ipin Joṣua 15

Wo Joṣua 15:10 ni o tọ