Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 14:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Mose bá búra ní ọjọ́ náà pé, ‘Dájúdájú, gbogbo ibi tí ẹsẹ̀ rẹ ti tẹ̀ ni yóo jẹ́ ìpín fún ọ ati fún àwọn ọmọ rẹ títí lae, nítorí pé o ti fi tọkàntọkàn tẹ̀lé OLUWA Ọlọrun mi.’

Ka pipe ipin Joṣua 14

Wo Joṣua 14:9 ni o tọ