Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 14:10 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA ti dá ẹ̀mí mi sí, gẹ́gẹ́ bí ó ti wí, láti nǹkan bí ọdún marunlelogoji tí OLUWA ti sọ ọ̀rọ̀ yìí fún Mose nígbà tí àwọn ọmọ Israẹli ń rìn ninu aṣálẹ̀. Nisinsinyii, mo ti di ẹni ọdún marundinlaadọrun,

Ka pipe ipin Joṣua 14

Wo Joṣua 14:10 ni o tọ