Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 14:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹni ogoji ọdún ni mí nígbà tí Mose iranṣẹ OLUWA rán mi láti Kadeṣi Banea láti ṣe amí ilẹ̀ náà. Bí ọkàn mi ti rí gan-an nígbà náà ni mo ṣe ròyìn fún un.

Ka pipe ipin Joṣua 14

Wo Joṣua 14:7 ni o tọ