Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 14:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ kan àwọn ẹ̀yà Juda wá sí ọ̀dọ̀ Joṣua ní Giligali. Ọkunrin kan ninu wọn tí ń jẹ́ Kalebu, ọmọ Jefune, ará Kenisi bá sọ fún un pé, “Ǹjẹ́ o mọ ohun tí OLUWA sọ fún Mose eniyan Ọlọrun ní Kadeṣi Banea nípa àwa mejeeji?

Ka pipe ipin Joṣua 14

Wo Joṣua 14:6 ni o tọ