Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 14:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Orúkọ Heburoni tẹ́lẹ̀ ni Kiriati Ariba; Ariba yìí ni ẹni tí ó jẹ́ alágbára jùlọ ninu àwọn òmìrán tí à ń pè ní Anakimu.Àwọn eniyan náà sì sinmi ogun jíjà ní ilẹ̀ náà.

Ka pipe ipin Joṣua 14

Wo Joṣua 14:15 ni o tọ