Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 14:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Bẹ́ẹ̀ ni Heburoni di ilẹ̀ ìní Kalebu, ọmọ Jefune, ará Kenisi títí di òní olónìí, nítorí pé ó fi tọkàntọkàn tẹ̀lé OLUWA Ọlọrun Israẹli.

Ka pipe ipin Joṣua 14

Wo Joṣua 14:14 ni o tọ