Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 10:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà náà ni àwọn ọba Amori maraarun, ọba Jerusalẹmu, ti Heburoni, ti Jarimutu, ti Lakiṣi, ati ti Egiloni parapọ̀, wọ́n kó gbogbo àwọn ọmọ ogun wọn jọ. Wọ́n lọ dó ti Gibeoni, wọ́n sì ń bá a jagun.

Ka pipe ipin Joṣua 10

Wo Joṣua 10:5 ni o tọ