Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 10:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ náà gan-an ni Joṣua gba ìlú Makeda, ó sì fi idà pa àwọn eniyan inú rẹ̀ ati ọba wọn. Gbogbo àwọn tí wọ́n wà níbẹ̀ ni ó parun, kò dá ẹnikẹ́ni sí. Bí ó ti ṣe sí ọba Jẹriko náà ló ṣe sí ọba Makeda.

Ka pipe ipin Joṣua 10

Wo Joṣua 10:28 ni o tọ