Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 10:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí oòrùn ń lọ wọ̀, Joṣua pàṣẹ pé kí wọ́n já òkú wọn lulẹ̀ kí wọ́n sì sọ wọ́n sinu ihò tí wọ́n sápamọ́ sí, wọ́n sì yí òkúta ńlá dí ẹnu ihò náà. Ó wà níbẹ̀ títí di òní olónìí.

Ka pipe ipin Joṣua 10

Wo Joṣua 10:27 ni o tọ