Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 10:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Oòrùn bá dúró jẹ́ẹ́, òṣùpá náà sì dúró jẹ́ẹ́, títí tí àwọn ọmọ Israẹli fi gbẹ̀san tán lára àwọn ọ̀tá wọn. Wọ́n kọ ọ́ sinu ìwé Jaṣari pé, oòrùn dúró ní agbede meji ojú ọ̀run, kò sì tètè wọ̀ fún bí odidi ọjọ́ kan.

Ka pipe ipin Joṣua 10

Wo Joṣua 10:13 ni o tọ