Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣua 10:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ tí OLUWA fi àwọn ará Amori lé àwọn ọmọ Israẹli lọ́wọ́, Joṣua bá OLUWA sọ̀rọ̀ lójú gbogbo Israẹli, ó ní,“Ìwọ oòrùn, dúró jẹ́ẹ́ ní Gibeoni.Ìwọ òṣùpá, sì dúró jẹ́ẹ́ ní àfonífojì Aijaloni.”

Ka pipe ipin Joṣua 10

Wo Joṣua 10:12 ni o tọ