Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joẹli 2:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Iná ń jó àjórun níwájú wọn,ahọ́n iná ń yọ lálá lẹ́yìn wọn.Ilẹ̀ náà dàbí ọgbà Edẹni níwájú wọn,ṣugbọn lẹ́yìn wọn, ó dàbí aṣálẹ̀ tí ó ti di ahoro,kò sì sí ohun tí yóo bọ́ lọ́wọ́ wọn.

Ka pipe ipin Joẹli 2

Wo Joẹli 2:3 ni o tọ