Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joẹli 2:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Yóo jẹ́ ọjọ́ òkùnkùn ati ìbànújẹ́,ọjọ́ ìkùukùu ati òkùnkùn biribiri.Àwọn ọmọ ogun yóo bo gbogbo òkè ńlá,bí ìgbà tí òkùnkùn bá ń ṣú bọ̀.Irú rẹ̀ kò ṣẹlẹ̀ rí ní ìgbà àtijọ́,bẹ́ẹ̀ ni irú rẹ̀ kò sì tún ní ṣẹlẹ̀ mọ́ títí lae.

Ka pipe ipin Joẹli 2

Wo Joẹli 2:2 ni o tọ