Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jobu 5:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn tí ebi ń pa níí jẹ ìkórè oko rẹ̀,bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ààrin ẹ̀gúnni ó ti mú un jáde,àwọn olójúkòkòrò a sì máa wá ohun ìní rẹ̀ kiri.

Ka pipe ipin Jobu 5

Wo Jobu 5:5 ni o tọ