Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jobu 32:20-22 BIBELI MIMỌ (BM)

20. Mo níláti sọ̀rọ̀ kí ara lè rọ̀ mí,mo gbọdọ̀ la ẹnu mi kí n sì dáhùn.

21. N kò ní ṣe ojuṣaaju ẹnikẹ́ni,bẹ́ẹ̀ ni n kò sì ní gbèjà eniyan.

22. Nítorí n kò mọ bí wọ́n ṣe ń pọ́n eniyan,kí Ẹlẹ́dàá mi má baà pa mí run ní kíá.

Ka pipe ipin Jobu 32