Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jobu 32:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Àwọn ọkunrin mẹtẹẹta náà kò dá Jobu lóhùn mọ́, nítorí pé ó jẹ́ olódodo lójú ara rẹ̀.

2. Elihu, ọmọ Barakeli, ará Busi, ní ìdílé Ramu bá bínú sí Jobu, nítorí pé ó dá ara rẹ̀ láre dípò Ọlọrun.

Ka pipe ipin Jobu 32