Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jobu 26:5-7 BIBELI MIMỌ (BM)

5. “Àwọn òkú wárìrì nísàlẹ̀.Omi ati àwọn olùgbé inú rẹ̀ pẹlu ń gbọ̀n rìrì.

6. Kedere ni isà òkú rí níwájú Ọlọrun,bẹ́ẹ̀ ni ìparun kò farasin.

7. Ó na ìhà àríwá sórí òfuurufú,ó sì so ayé rọ̀ sí òfuurufú.

Ka pipe ipin Jobu 26