Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jobu 14:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí eniyan bá kú, ǹjẹ́ yóo tún jí mọ́?N óo dúró ní gbogbo ọjọ́ làálàá mi,n óo máa retí, títí ọjọ́ ìdáǹdè mi yóo fi dé.

Ka pipe ipin Jobu 14

Wo Jobu 14:14 ni o tọ