Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 9:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Orí mi ìbá jẹ́ kìkì omi,kí ojú mi sì jẹ́ orísun omijé;tọ̀sán-tòru ni ǹ bá fi máa sọkún,nítorí àwọn eniyan mi tí ogun ti pa.

Ka pipe ipin Jeremaya 9

Wo Jeremaya 9:1 ni o tọ