Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 8:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Báwo ni ẹ ṣe lè wí pé,‘Ọlọ́gbọ́n ni wá,a sì mọ òfin OLUWA?’Ṣugbọn àwọn akọ̀wé ti fi gègé irọ́ wọn sọ ọ́ di èké.

Ka pipe ipin Jeremaya 8

Wo Jeremaya 8:8 ni o tọ