Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 52:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọdún kẹtadinlogoji lẹ́yìn tí a ti mú Jehoiakini, ọba Juda lọ sí ìgbèkùn, ní ọjọ́ kẹẹdọgbọn oṣù kejila ọdún náà Efilimerodaki, ọba Babiloni yẹ ọ̀rọ̀ Jehoiakini wò ní ọdún tí ó gorí oyè, ó sì pàṣẹ pé kí á tú u sílẹ̀ kúrò ní àtìmọ́lé.

Ka pipe ipin Jeremaya 52

Wo Jeremaya 52:31 ni o tọ