Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 52:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọdún kẹtalelogun tí Nebukadinesari jọba, Nebusaradani, olórí àwọn tí wọn ń ṣọ́ ọba, kó ojilelẹẹdẹgbẹrin ó lé marun-un (745) eniyan lára àwọn Juu. Gbogbo àwọn eniyan tí wọn kó lẹ́rú jẹ́ ẹgbaaji lé ẹgbẹta (4,600).

Ka pipe ipin Jeremaya 52

Wo Jeremaya 52:30 ni o tọ