Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 51:34 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nebukadinesari ọba Babiloni ti run Jerusalẹmu,ó ti tẹ̀ ẹ́ mọ́lẹ̀,ó ti sọ ọ́ di ohun èlò òfìfo,ó gbé e mì bí erinmi,ó ti kó gbogbo ohun àdídùn inú rẹ̀ jẹ ní àjẹrankùn,ó ti da ìyókù nù.

Ka pipe ipin Jeremaya 51

Wo Jeremaya 51:34 ni o tọ