Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 51:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Babiloni dàbí ibi ìpakà, tí a tẹ̀ mọ́lẹ̀ nígbà tí à ń pa ọkà.Láìpẹ́ ọ̀tá yóo dà á wó, yóo sì di àtẹ̀mọ́lẹ̀.Èmi OLUWA àwọn ọmọ ogun, Ọlọrun Israẹli ni mo sọ bẹ́ẹ̀.

Ka pipe ipin Jeremaya 51

Wo Jeremaya 51:33 ni o tọ