Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 50:6 BIBELI MIMỌ (BM)

“Àwọn eniyan mi dàbí aguntan tí ó sọnù, àwọn olùṣọ́ wọn ti ṣì wọ́n lọ́nà. Wọ́n ń lọ síhìn-ín, sọ́hùn-ún lórí òkè, wọ́n ń ti orí òkè kéékèèké bọ́ sí orí òkè ńláńlá; wọ́n ti gbàgbé ọ̀nà agbo wọn.

Ka pipe ipin Jeremaya 50

Wo Jeremaya 50:6 ni o tọ