Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 50:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọn yóo bèèrè ọ̀nà Sioni, wọn yóo kọjú sibẹ, wọn yóo sì wí pé: ‘Ẹ wá, ẹ jẹ́ kí á darapọ̀ mọ́ OLUWA, kí á sì bá a dá majẹmu ayérayé, tí a kò ní gbàgbé mọ́ títí ayé.’

Ka pipe ipin Jeremaya 50

Wo Jeremaya 50:5 ni o tọ