Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 50:45 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, ẹ gbọ́ ète tí èmi OLUWA pa lórí Babiloni, ati èrò mi lórí àwọn ará Kalidea: A óo kó agbo ẹran wọn lọ tọmọtọmọ; ibùjẹ ẹran wọn yóo sì parun nítorí tiwọn.

Ka pipe ipin Jeremaya 50

Wo Jeremaya 50:45 ni o tọ