Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 50:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo ẹ̀yin tí ẹ yí i ká, ẹ hó bò ó, ó ti jọ̀wọ́ ara rẹ̀ sílẹ̀. Àwọn ibi ààbò rẹ̀ ti wó, àwọn odi rẹ̀ sì ti wó lulẹ̀. Nítorí ẹ̀san OLUWA ni, ẹ gbẹ̀san lára rẹ̀; ẹ ṣe sí i bí òun náà ti ṣe sí àwọn ẹlòmíràn.

Ka pipe ipin Jeremaya 50

Wo Jeremaya 50:15 ni o tọ