Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 49:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Wò ó! N óo kó ìpayà bá ọ,láti ọ̀dọ̀ gbogbo àwọn tí wọ́n yí ọ ká;èmi OLUWA Ọlọrun àwọn ọmọ ogun ni mo sọ bẹ́ẹ̀.Gbogbo yín ni yóo fọ́nká,tí olukuluku yóo sì yà sí ọ̀nà tirẹ̀,kò sì ní sí ẹni tí yóo kó àwọn tí ń sá fún ogun jọ.

Ka pipe ipin Jeremaya 49

Wo Jeremaya 49:5 ni o tọ