Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 49:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ohun tí OLUWA sọ nípa àwọn ará Amoni nìyí: Ó ní,“Ṣé Israẹli kò lọ́mọ ni?Tabi kò ní àrólé?Kí ló dé tí àwọn tí ń bọ Milikomu ṣe gba ilẹ̀ ẹ̀yà Gadi,tí wọ́n sì fi àwọn ìlú Gadi ṣe ibùjókòó?

Ka pipe ipin Jeremaya 49

Wo Jeremaya 49:1 ni o tọ