Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 46:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ má bẹ̀rù, ẹ̀yin ọmọ Jakọbu, iranṣẹ mi,nítorí pé mo wà pẹlu yín.N óo run gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè tí mo le yín lọ,ṣugbọn n kò ní pa yín run.Bí ó bá tọ́ kí n jẹ yín níyà, n óo jẹ yín níyà,kìí ṣe pé n óo fi yín sílẹ̀ láìjẹ yín níyà.Èmi OLUWA ni mo sọ bẹ́ẹ̀.”

Ka pipe ipin Jeremaya 46

Wo Jeremaya 46:28 ni o tọ