Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 46:27 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ṣugbọn ẹ má bẹ̀rù, ẹ̀yin ọmọ Jakọbu, iranṣẹ mi,ọmọ Israẹli, ẹ má fòyà;n óo gbà yín là láti ọ̀nà jíjìn,n óo kó arọmọdọmọ yín yọ ní ilẹ̀ ìgbèkùn.Ẹ̀yin ọmọ Jakọbu, ẹ óo pada máa gbé ní ìrọ̀rùn.Kò sì ní sí ẹni tí yóo dẹ́rù bà yín.

Ka pipe ipin Jeremaya 46

Wo Jeremaya 46:27 ni o tọ