Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 44:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí ló dé tí ẹ fi ń fi iṣẹ́ ọwọ́ yín bí mi ninu, tí ẹ̀ ń sun turari sí àwọn oriṣa ní ilẹ̀ Ijipti, níbi tí ẹ̀ ń gbé? Ṣé ẹ fẹ́ kí n pa yín run, kí ẹ di ẹni ẹ̀sín láàrin gbogbo orílẹ̀-èdè ayé ni ẹ ṣe ń ṣe báyìí?

Ka pipe ipin Jeremaya 44

Wo Jeremaya 44:8 ni o tọ