Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 41:5 BIBELI MIMỌ (BM)

àwọn ọgọrin eniyan kan wá láti Ṣekemu, Ṣilo ati láti Samaria pẹlu irùngbọ̀n wọn ní fífá, wọ́n fa agbádá wọn ya, wọ́n sì ṣá ara wọn lọ́gbẹ́. Wọ́n mú ọrẹ ẹbọ ati turari lọ́wọ́ wá sí Tẹmpili OLUWA.

Ka pipe ipin Jeremaya 41

Wo Jeremaya 41:5 ni o tọ