Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 37:9 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA ní kí wọn sọ fún Sedekaya ati àwọn ará Juda kí wọn má tan ara wọn jẹ, kí wọn má sì rò pé àwọn ará Kalidea kò ní pada wá sọ́dọ̀ wọn mọ́, nítorí wọn kò ní lọ.

Ka pipe ipin Jeremaya 37

Wo Jeremaya 37:9 ni o tọ