Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 37:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ará Kalidea sì ń pada bọ̀ wá gbé ogun ti ìlú yìí; wọn yóo gbà á, wọn yóo sì dáná sun ún.

Ka pipe ipin Jeremaya 37

Wo Jeremaya 37:8 ni o tọ