Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 32:24 BIBELI MIMỌ (BM)

“ ‘Wo bí àwọn ọ̀tá ti mọ òkítì sí ara odi wa láti gba ìlú wa. Nítorí ogun, ìyàn ati àjàkálẹ̀ àrùn, a óo fi ìlú yìí lé àwọn ará Kalidea tí wọn gbógun tì í lọ́wọ́. Ohun tí o wí ṣẹ, o sì ti rí i.

Ka pipe ipin Jeremaya 32

Wo Jeremaya 32:24 ni o tọ