Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 32:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n dé ilẹ̀ náà, wọ́n sì gbà á; ṣugbọn wọn kò gbọ́rọ̀ sí ọ lẹ́nu, wọn kò sì pa òfin rẹ mọ́. Wọn kò ṣe ọ̀kan kan ninu gbogbo ohun tí o pàṣẹ fún wọn láti máa ṣe; nítorí náà ni o ṣe mú kí gbogbo ibi tí ó ṣẹlẹ̀ sí wọn bá wọn!

Ka pipe ipin Jeremaya 32

Wo Jeremaya 32:23 ni o tọ