Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 3:1 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA ní, “Ṣé bí ọkọ bá kọ iyawo rẹ̀ sílẹ̀,tí iyawo náà sì kó jáde nílé ọkọ,tí ó lọ fẹ́ ẹlòmíràn,ṣé ọkọ rẹ̀ àkọ́kọ́ lè tún lọ gbà á pada?Ṣé ilẹ̀ náà kò ní di ìbàjẹ́?Lẹ́yìn tí ẹ ti ṣe àgbèrè pẹlu ọpọlọpọ olólùfẹ́;ẹ wá fẹ́ pada sọ́dọ̀ mi?

Ka pipe ipin Jeremaya 3

Wo Jeremaya 3:1 ni o tọ