Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 24:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Èso ọ̀pọ̀tọ́ tí ó wà ninu apẹ̀rẹ̀ kinni dára gbáà, ó dàbí èso ọ̀pọ̀tọ́ tí ó kọ́kọ́ pọ́n. Èso ọ̀pọ̀tọ́ tí ó wà ninu apẹ̀rẹ̀ keji ti rà patapata tóbẹ́ẹ̀ tí kò ṣe é jẹ. p

Ka pipe ipin Jeremaya 24

Wo Jeremaya 24:2 ni o tọ