Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 21:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọ̀rọ̀ tí Jeremaya gbọ́ lẹ́nu OLUWA nìyí nígbà tí ọba Sedekaya rán Paṣuri, ọmọ Malikaya, ati alufaa Sefanaya, ọmọ Maaseaya, sí i;

Ka pipe ipin Jeremaya 21

Wo Jeremaya 21:1 ni o tọ