Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 2:26 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA ní, “Bí ojú tíí ti olè nígbà tí ọwọ́ bá tẹ̀ ẹ́,bẹ́ẹ̀ ni ojú yóo tì yín, ẹ̀yin ọmọ Israẹli.Àtẹ̀yin ati àwọn ọba yín, ati àwọn ìjòyè yín,ati àwọn alufaa yín, ati àwọn wolii yín;

Ka pipe ipin Jeremaya 2

Wo Jeremaya 2:26 ni o tọ