Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 17:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí àparò tíí pa ẹyin ẹlẹ́yinbẹ́ẹ̀ ni ẹni tí ó fi èrú kó ọrọ̀ jọ.Ọrọ̀ yóo lọ mọ́ ọn lọ́wọ́ lọ́sàn-án gangan,nígbẹ̀yìn yóo di òmùgọ̀.

Ka pipe ipin Jeremaya 17

Wo Jeremaya 17:11 ni o tọ