Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 16:21 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA ní, “Nítorí náà, wò ó, n óo jẹ́ kí wọn mọ̀;àní sẹ́, n óo jẹ́ kí wọ́n mọ agbára ati ipá mi;wọn yóo sì mọ̀ pé orúkọ mi ni OLUWA.”

Ka pipe ipin Jeremaya 16

Wo Jeremaya 16:21 ni o tọ