Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 16:15 BIBELI MIMỌ (BM)

ṣugbọn wọn yóo máa búra pé, ‘Bí OLUWA tí ń bẹ, ẹni tí ó kó àwọn ọmọ Israẹli jáde láti ilẹ̀ àríwá ati láti gbogbo orílẹ̀-èdè tí ó lé wọn lọ.’ N óo mú wọn pada sórí ilẹ̀ wọn, ilẹ̀ tí mo fún àwọn baba wọn.”

Ka pipe ipin Jeremaya 16

Wo Jeremaya 16:15 ni o tọ