Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 15:4 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo sọ wọ́n di ohun tí ó bani lẹ́rù fún gbogbo ìjọba ilẹ̀ ayé, nítorí ohun tí Manase, ọmọ Hesekaya, ọba Juda, ṣe ní Jerusalẹmu.”

Ka pipe ipin Jeremaya 15

Wo Jeremaya 15:4 ni o tọ