Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 13:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí ni ẹ óo máa wí nígbà tí OLUWA bá mú àwọn tí ẹ fi ṣe ọ̀rẹ́,tí ó fi wọ́n jọba le yín lórí?Ǹjẹ́ ìnira kò ní ba yín, bí ìrora obinrin tí ń rọbí?

Ka pipe ipin Jeremaya 13

Wo Jeremaya 13:21 ni o tọ